Àwọn ọnà tí a lè fi mọ ẹbi eke

Lati ọwọ Bobby Conway 

 

Ọlọ́run mọ pe a ní ẹbi òtítọ tí ó pọ tó ti o yí wa ká ju kí a tún máa ṣe àníyàn lórí àwọn àwọn ẹbí miran lọ, ní o setan láti fi ẹsun kan wá. Sugbọn báwo nì a ṣe lè mọ bóyá ẹbí tí a ń ní jẹ òtító àbí èké? Kini ara àwọn àmì tí ó yẹ kí a sọra fún? Bí ó tilẹ jẹ pe awon ẹsun yìí kò ní ìnira, àwọn ọnà mẹta tí a lè fi dá ẹbi èké mọ ni yìí.  

 

Àkọ́kọ́, ẹbi èké máa ń fi ara han bí ẹbi tòótọ́  

Irúfẹ ẹbi èké báyìí kii se ẹbi tootọ, nítorí a ó jẹbi ẹsẹ ìrékọjá lóòótọ, ṣùgbọ́n ó jẹ isesi tí ó ń fihan bí ẹni pé a jẹbi nigbati a kò jẹbi. Nínú àṣà òde òní, ẹbi miran wá lórí àwọn tó kùnà  láti tẹle ìwà ìyípo ayé tí ìsinsìnyí. Tiwa jẹ àṣà tí ipede rẹ lè jẹ faramo eto ìwà wá tàbí kí o parẹ́. A sì  ń tesiwaju láti máa wò áwon tí wọn ní òye Kristẹni ń bá ara wọn nínú isoro èké láti àwọn ajini lẹsẹ òde, ó dàbí ẹni pé ohun méjì yii:  faramo eto ìwà wá tàbí kí o parẹ́  nikan ni wọn ń fi lọ ni. Nípa fífi ìṣòro èké yìí hàn, a lè ní ìrètí yiyago fún wọn. Àṣà tí òde òní ń pè búburú ni rere, àwọn tí kò bá faramọ ìṣe ìwà òde òní tí wọn ń sọ di ẹlẹbi tòótọ 

Èkejì, ẹbi èké máa ń fà àníyàn àti ìgbọkan sókè tó ń rí ní lára  

John Steinbeck gbe ọrọ ẹbi èké yẹwo nígbà tí ó wí pé, “Mi ò jí ohunkóhun gbé rí ní ayé mi. Kilode tí mo fi má ń ní ìdálébi ọkàn bí mo bá ń gba ọdọ àwọn ọlópàá irona kọjá?”¹ irú ìdálébi èké tí kò ní itumọ lè sọni di ojo, kò sí ṣe wá ní ire kankan. Ìdálébi èké jẹ àkójọ pọ aburu nini ìdálébi nígbàtí ọkàn wa mọ òtítọ. Ó ṣe ní laanu pé àwọn kan má ń ka oji ẹbi tí kìí ṣe tiwọn paapa – tàbí tí kii se òtító. Ó jé ẹbi èké ponbele. Ó jé ẹbi èké tí ó ń farahàn bí òtító tí ó ń gbìn àníyàn àti ìgbọkan sókè sínú ọkàn irufẹ ẹni bẹẹ. ̀  

Ẹkẹta, ẹbi èké máa ń ṣe ìsọra apọju gidigidi 

O ti di mímọ pé kí Martin Luther tó ṣe ìràpadà, ó ti wà iforiji gidigidi. Ó wí pé, mo máa ń ṣe ijwọ ẹsẹ loorekoore, mo sì má ń gba ìjìyà tí mo fún ara mi lai sẹ ọkan kù, ẹri ọkàn mi kò ní ìsinmi ó sì máa ń bá ọ wí pé, ‘Oo tíi ṣe èyí lọnà tí ó tọ. O ò ní iwopalẹ ọkan tó. O yọ èyí silẹ nínú ijẹwọ rẹ. “¹. Kò jọni lójú, ó jẹ ẹni tó ń dójú kọ ọpọlọpọ ẹbi èké. Àwọn tí wọn ń dójú kọ ìdálébi yìí jù ni àwọn tí wọn jijakadi pẹlu  

_________________________ 

 Walter von Loewenich, Martin Luther: The Man and His Work, p. 76 (Minneapolis: Augsburg), 1986. 

Ìwà isesi aaganna tó jẹ dandan, (OCD). Irú àwọn bẹẹ, bóyá Luther náà wá lára wọn, n tiraka pẹlu ìwà kàńpá títí dé orí ohun tó kéré jù. Ní ìyọrísí èyí, èyí lè fà kí ibasepọ ènìyàn pẹlu Ọlórun di ailojuutu, sì ohun tó yẹ kó jẹ ìgbádùn.  

Ní ìkẹyìn, olórí orísun ìdálébi ni esu, bàbà irọ tí ó ń féràn láti fi ènìyàn sún (Ifihàn 12:10). Bí ó bá jẹ ẹni tí ó máa ń ní ìdálébi yii, èyí ni ikilọ kékeré tí ó níláti mọ. Ó ṣe ní laanu pé àwọn tí wọn tí jìyà idalẹbi yìí kò ní ọkàn pupọ fún ọrọ yii, wọn si ti fi adagba rẹ rọ sí odikeji, tí wọn sì ń kọ ebi yìí papọ.  

Èyí kò ní ọgbón nínú tàbí dára.  

Ohun tí ó dára jù ni lati mọ ìyàtọ. 

Àwọn ètò tí a là kalẹ
Kilode tí Ọlọ́run fi dá Sátánì nígbà tí Ó mọ pe yoo da ibi sílẹ̀? (crossexamined.org)|Rajkumar Richard)
https://crossexamined.org/nígbàtí-oludije-rẹ-ba-se-eru-kini-ki-o-se? | John Ferrer
Apá kejì, “Nigbati Oludije rẹ bá ṣe ẹrú, Kini kí o ṣe?” (crossexamined.org) |John Ferrer