Tani Crossexamined?

CrossExamined ní ìbáṣep  p lú àwọn iṣ  ìránṣ  Kristẹni mìíràn, àwọn Ònkọwé àti àwọn olùkéde g g  ọ̀ẹ̀ẹ́ẹ́ẹ́ẹ́bí a ṣe ń gbèrò láti gbé àwọn Kristẹni ró láti yè, ní ìm , gbéjà ìgbàgb  wọn àti nípa mímú àṣà wa tó ọ̀ọ́dáńt  lò àti  àwọn èrò òye ayé nípa ṣíṣe àgbékal  àwọn àríyànjiyàn to gba èrò tí ó sì ní òye nínú àti  rí    ọ́ẹ̀ẹ̀fún  sìn Kristẹni. 

CrossExamined Áfíríkà di opó ìgbàgb àpósítélì mú g g bí gbólóhùn ìgbàgb wa :

CROSSEXAMINED MISSION

Ẹ̀sìn Kristẹni kò lè jẹ́ òtítọ́, tàbí òye ayé kankan (àìgbàgbọ́-nínú-Ọlọrun pẹ̀lú), bí òtítọ́ bá fì sí apá kan tàbí “ó jẹ́ òtítọ́ fún ìwọ ṣùgbọ́n tí kò rí bẹ́ẹ̀ fún mi”.

Bí ìṣe ìyanu kò bá ṣẹlẹ̀, ó jásí pé òtúbáńtẹ́ ni ẹ̀sìn Kristẹni. A ní ìgbàgbọ́ yàtọ̀ pé iṣẹ́-ìyanu seé ṣe, iṣẹ ìyanu tí ó ga jùlọ tí ṣẹlẹ̀, a sì ní ẹ̀rí sayẹnsi fún un.

Kò lè sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láì jẹ́ pé Ọlọ́run wà. A gbàgbọ́ pé a lè gbé àríyànjiyàn mẹ́ta kan kalẹ̀ fún ìwàláàyè Ọlọ́run, tí sayẹnsi méjì àti ti ìmọ̀ òye kan, láì tọ́ka sínú Bíbélì.

Àyàfi bí òtítọ́ bá wà, bí Ọlọ́run bá wà, tí iṣẹ́ ìyanu bá ṣì ṣeé ṣe, èké ni Májẹmú Tuntun. Ṣùgbọ́n lẹ́yìn fífi àwọn kókó wọnyẹn múlẹ, a lè pèṣè àwọn ìdí láti gbàgbọ́ pé Májẹmú Tuntun jẹ́ òtítọ́ nípa ìtàn àti pé Jéṣù kú lóòótọ́, Ó ṣì jí nde kúrò nínú òkú láti gba ẹdá ènìyàn là. Ǹí àfikún, òkodoro májẹmú tuntun tọ́ka ṣí òkodoro májẹmú láéláé.

CrossExamined Awọn italaya

Òtít Òdì

Òtít dúró lórí ẹs r méjì; a ń wádìí r ni, a kìí pinnu r . Ìtànjẹ ni òtít òdì, yálà nípa t tàbí nípa ọ́ẹ̀ẹ̀ẹ̀ẹ̀ọ́ọ̀ẹ̀àìmọkan. Báyìí, ju àt yìnwá lọ, Ìtànjẹ ti tàn kál káàkiri il Áfíríkà.

Àwọn èrò ìtakò nípa dá ènìyàn, ayé àti Ọl run

Láb píp sí í ìparun-àdám , àjàkál àrùn, rù, ìjà fún òtít tí súyọ. Kíni òtít nípa àgbáyé wa, nípa dá ẹ́ọ̀ọ́ẹ̀ẹ̀ọ́ọ́ẹ̀ènìyàn àti Ọl run. Ní CrossExamined, a máa ń ja ìjàkadì p lú àwọn ìbéèrè kan tó ṣe pàtàkì nípa orísun, ọ́ẹ̀kókó, òfin ìwà àti ayérayé.

Àìsí-ní-ìgbáradí fún ìṣe àṣà

Ọ̀ọ̀ọ̀ẹ̀ẹ́ẹ́ọ́ìbéèrè náà ni pé, ǹj ó ní í ṣe p lú bí ìgbàgb wa ṣe yé wa sí? A gbàgb pé b ni ó rí. Onírúurú àwọn ẹ́ẹ̀ọ́ọ́ẹ́ẹ̀àṣà ni ó máa ń gbé orísìírísìí èrò lárugẹ, yálà ó dúró lórí ìgbàgb tàbí ó níí ṣe p lú òtít . Ní ọ́ẹ̀ọ́CrossExamined Áfíríkà, a ń gbèrò láti fún ọ ní ìgbáradì láti kópa nínú àwọn ìf rọ-jomitoro- r tí ó ṣe ọ̀ọ̀ọ̀pàtàkì w nyí ní nà tí ó dáńt tí ó sì múná dóko.